Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Music: Chambers for musicians in the temple, in Ezekiel's vision
Àwọn ẹsẹ nípa Chambers for musicians in the temple, in Ezekiel's vision
Lẹ́yìn náà ó wọn àgbàlá, ó jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ó sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ní ìbú. Pẹpẹ sì wà ní iwájú tẹmpili.