Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Murmuring: Elijah

1 ẹsẹ · 31 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Elijah

  1. nígbà tí òun tìkára rẹ̀ sì lọ ní ìrìn ọjọ́ kan sí aginjù, ó sì wá sí ibi igi ọwọ̀ kan, ó sì jókòó lábẹ́ rẹ̀, ó sì gbàdúrà kí òun bá le kú, wí pé, “Mo ti ní tó, Olúwa, gba ẹ̀mí mi kúrò; nítorí èmi kò sàn ju àwọn baba mi lọ.”