Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mother-in-Law: Peter's, healed by Jesus
Àwọn ẹsẹ nípa Peter's, healed by Jesus
Ìyá ìyàwó Simoni tí ó dùbúlẹ̀ àìsàn ibà, wọ́n sì sọ fún Jesu nípa rẹ̀.
Ó sì tọ̀ ọ́ lọ, ó fà á lọ́wọ́, ó sì gbé e dìde; lójúkan náà ibà náà fi sílẹ̀, ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún wọn.