Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mordecai: Foster father of Esther

1 ẹsẹ · 4 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Foster father of Esther

  1. Mordekai ní arákùnrin kan ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Hadassa, ẹni tí ó tọ́ dàgbà nítorí tí kò ní baba bẹ́ẹ̀ sì ni kò ní ìyá. Obìnrin yìí, ẹni tí a tún mọ̀ sí Esteri, ó dára ó sì lẹ́wà, Mordekai mú u gẹ́gẹ́ bí ọmọ rẹ̀ nígbà tí baba àti ìyá rẹ̀ ti kú.