Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Micah: 3. Called Micha, son of Mephibosheth

5 ẹsẹ · 5 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 3. Called Micha, son of Mephibosheth

  1. Mefiboṣeti sì ní ọmọ kékeré kan, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Mika. Gbogbo àwọn tí ń gbé ní ilé Ṣiba ni ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún Mefiboṣeti.

  2. Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali tí ó jẹ́ baba Mika.

  3. Àwọn ọmọ Mika: Pitoni, Meleki, Tarea, àti Ahasi.

  4. Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali, tí ó jẹ́ baba Mika.

  5. Àwọn ọmọ Mika: Pitoni. Meleki, Tarea àti Ahasi.