Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mesha: 1. King of Moab. Tributary to Ahad 2 ẹsẹ · 4 abala Wá "Mesha" Gbogbo 5 1. King of Moab. Tributary to Ahad 2 2. Son of Caleb 1 3. A place in possession of the Joktanites 1 4. A Benjamite 1 Àwọn ẹsẹ nípa 1. King of Moab. Tributary to Ahad 2 Ọba 3:4Nísinsin yìí Meṣa ọba Moabu ń sin àgùntàn, ó sì gbọdọ̀ fi fún ọba Israẹli pẹ̀lú ọ̀kẹ́ márùn-ún ọ̀dọ́-àgùntàn àti pẹ̀lú irun ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) àgbò.2 Ọba 3:5Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ikú Ahabu, ọba Moabu ṣọ̀tẹ̀ lórí ọba Israẹli.