Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Man: Received dominion over other creatures

3 ẹsẹ · 114 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Received dominion over other creatures

  1. Ìwọ mú un jẹ ọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ; ìwọ sì fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀:

  2. àwọn agbo àgùntàn àti àwọn màlúù, àti ẹranko igbó,

  3. ẹyẹ ojú ọrun, àti ẹja inú Òkun, àti ohun tí ń wẹ nínú ipa Òkun.