Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Geshur: Absalom takes refuge in, after the murder of Amnon
Àwọn ẹsẹ nípa Absalom takes refuge in, after the murder of Amnon
Absalomu sì sá, ó sì tọ Talmai lọ, ọmọ Ammihudu, ọba Geṣuri. Dafidi sì ń káàánú nítorí ọmọ rẹ̀ lójoojúmọ́.
Absalomu sì sá, ó sì lọ sí Geṣuri ó sì gbé ibẹ̀ lọ́dún mẹ́ta.