Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Egyptians: Eligible to membership in Israelitish congregation in the third generation
Àwọn ẹsẹ nípa Eligible to membership in Israelitish congregation in the third generation
Ìwọ kò gbọdọ̀ kórìíra ará Edomu kan nítorí arákùnrin rẹ ni. Ìwọ kò gbọdọ̀ kórìíra ará Ejibiti, nítorí o gbé gẹ́gẹ́ bí àjèjì ní ilẹ̀ rẹ̀.
Ìran kẹta àwọn ọmọ tí a bí fún wọn lè wọ ìpéjọ Olúwa.