Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Covenants: Selling land

3 ẹsẹ · 31 abala

Wá "Covenants"

Àwọn ẹsẹ nípa Selling land

  1. Efroni sì dá Abrahamu lóhùn pé,

  2. “Gbọ́ tèmi Olúwa mi, irinwó (400) òsùwọ̀n owó fàdákà ni ilẹ̀ náà, ṣùgbọ́n kín ni ìyẹn já mọ láàrín àwa méjèèjì? Sá à sin òkú rẹ.”

  3. Abrahamu sì gbọ́ tí Efroni wí, Abrahamu sì wọn iye fàdákà náà fún Efroni, tí ó sọ ní etí àwọn ọmọ Hiti, irinwó (400) òsùwọ̀n ṣékélì fàdákà, tí ó kọjá lọ́dọ̀ àwọn oníṣòwò.