Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Burial: Burial of Gog requiring 7 months
Àwọn ẹsẹ nípa Burial of Gog requiring 7 months
“ ‘Fún oṣù méje ní ilé Israẹli yóò fi máa sìn wọ́n láti ṣe àfọ̀mọ́ ilẹ̀ náà.
Gbogbo ènìyàn ilẹ̀ náà yóò sìn wọ́n, ọjọ́ tí a yìn mi lógo yóò jẹ́ ọjọ́ ìrántí, ní Olúwa Olódùmarè wí.