Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Bashan: Invaded and taken by Hazael, king of Syria

2 ẹsẹ · 8 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Invaded and taken by Hazael, king of Syria

  1. Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, Olúwa ti bẹ̀rẹ̀ sí ní dín iye Israẹli kù. Hasaeli fi agbára jẹ ọba lórí àwọn ọmọ Israẹli ní gbogbo agbègbè wọn.

  2. Ìlà-oòrùn ti Jordani ni gbogbo ilẹ̀ ti Gileadi (ẹ̀kún ilẹ̀ ti ará Gadi, Reubeni, àti Manase) láti Aroeri, tí ó wà létí kòtò Arnoni láti ìhà Gileadi sí Baṣani.