Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa All Christians Should Be As Missionaries: The zeal of hypocrites should provoke to
Àwọn ẹsẹ nípa The zeal of hypocrites should provoke to
“Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin olùkọ́ òfin àti Farisi, ẹ̀yin àgàbàgebè! Nítorí ẹ̀yin rin yí ilẹ̀ àti òkun ká láti yí ẹnìkan lọ́kàn padà, ṣùgbọ́n ẹ̀yin ń sọ ọ́ di ọmọ ọ̀run àpáàdì ní ìlọ́po méjì ju ẹ̀yin pàápàá.