Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Aliens: Partially exempt from Jewish law

1 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Partially exempt from Jewish law

  1. Ẹ má ṣe jẹ ohun tí ó ti kú sílẹ̀. Ẹ lè fún àwọn àjèjì tí ń gbé ní èyíkéyìí nínú ìlú yín. Òun lè jẹ ẹ́ tàbí kí ẹ tà á fún àwọn àjèjì. Ṣùgbọ́n ènìyàn mímọ́ fún Olúwa Ọlọ́run yín ni ẹ̀yin jẹ́. Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe ewúrẹ́ nínú wàrà ìyá rẹ̀.