Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Afflictions Made Beneficial: In testing and exhibiting our sincerity
Àwọn ẹsẹ nípa In testing and exhibiting our sincerity
Ṣùgbọ́n òun mọ ọ̀nà tí èmi ń tọ̀, nígbà tí ó bá dán mí wò, èmi yóò jáde bí wúrà.
Nítorí ìwọ, Ọlọ́run, dán wa wò; ìwọ dán wa bí a tí ń dán fàdákà wò.
Iná ni a fi fọ́ fàdákà àti wúrà, ṣùgbọ́n Olúwa ló ń dán ọkàn wò.