Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Afflictions and Adversities: Mocking at 2 ẹsẹ · 5 abala Wá "Afflictions and Adversities" Gbogbo 526 Consolation in 287 Dispensation of God 166 Benefits of 63 Despondency in 28 Mocking at 2 Àwọn ẹsẹ nípa Mocking at Jobu 12:5Ó rọrùn fún ènìyàn láti fi ìbànújẹ́ ẹlòmíràn ṣe ẹlẹ́yà gẹ́gẹ́ bí ìpín àwọn ẹni tí ẹsẹ̀ wọn ṣetán láti yọ̀.Òwe 17:5Ẹnikẹ́ni tí ó bá sín olùpọ́njú jẹ, ó gan Ẹlẹ́dàá rẹ̀, ẹnikẹ́ni tí ń yọ̀ sí ìyọnu kò ní lọ láìjìyà.