Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Adullam: 2. An ancient city of Canaan
Àwọn ẹsẹ nípa 2. An ancient city of Canaan
Ní àkókò náà, Juda lọ kúrò lọ́dọ̀ àwọn arákùnrin rẹ̀ láti lọ dúró lọ́dọ̀ ọkùnrin ará Adullamu kan tí ń jẹ́ Hira.
ọba Libina, ọ̀kan ọba Adullamu, ọ̀kan
Jarmatu, Adullamu, Soko, Aseka,
Beti-Suri, Soko, Adullamu,
Sanoa, Adullamu àti àwọn ìletò o wọn, ní Lakiṣi àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Aseka àti àwọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Beerṣeba títí dé àfonífojì Hinnomu.
Èmi yóò sì mú àrólé kan wá sórí rẹ ìwọ olùgbé Meraṣa. Ẹni tí ó jẹ́ ògo Israẹli yóò sì wá sí Adullamu.