Jarmuth
31.7000, 34.9600 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Jarmuth
Nítorí náà Adoni-Sedeki ọba Jerusalẹmu bẹ Hohamu ọba Hebroni, Piramu ọba Jarmatu, Jafia ọba Lakiṣi àti Debiri ọba Egloni. Wí pe,
Àwọn ọba Amori márààrún, ọba Jerusalẹmu, Hebroni, Jarmatu, Lakiṣi àti Egloni, kó ara wọn jọ, wọ́n sì gòkè, àwọn àti gbogbo ogun wọn, wọ́n sì dojúkọ Gibeoni, wọ́n sì kọlù ú.
Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì mú àwọn ọba márààrún náà kúrò nínú ihò àpáta, àwọn ọba Jerusalẹmu, Hebroni, Jarmatu, Lakiṣi àti Egloni.
ọba Jarmatu, ọ̀kan ọba Lakiṣi, ọ̀kan
Jarmatu, Adullamu, Soko, Aseka,
ní Ẹni-Rimoni, ní Sora, ní Jarmatu,