Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Access to God: Follows upon reconciliation to God

2 ẹsẹ · 18 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Follows upon reconciliation to God

  1. Ẹ̀yin ya ara yín nípá kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run nígbà kan rí, ẹ jẹ́ ọ̀tá nínú ọkàn yín nítorí ìwà búburú yín.

  2. Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ó ti bá yín làjà nípa ara Kristi nípa ikú láti mú un yín lọ sí iwájú rẹ̀ ní mímọ́, aláìlábàwọ́n àti kúrò nínú ìdálẹ́bi,