Skip to content

Amorite

4 ẹsẹ · 11 ọmọ ẹbí

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Amorite

  1. Àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi,

  2. àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi,

  3. “Mo pa àwọn ará Amori run níwájú wọn gíga ẹni tí ó dàbí igi kedari. Òun sì le koko bí igi óákù mo pa èso rẹ̀ run láti òkè wá àti egbò rẹ̀ láti ìsàlẹ̀ wá.

  4. Èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá, mo sì sìn yín la aginjù já ní ogójì ọdún láti fi ilẹ̀ àwọn ará Amori fún un yín.