Fò sí àkóónú

Ahaziah

26 ẹsẹ · 5 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Jehoahaz, Azariah

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Ahaziah

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Jehoaṣi ọba Israẹli fi agbára mú Amasiah ọba Juda, ọmọ Joaṣi ọmọ Ahasiah ní Beti-Ṣemeṣi. Nígbà náà Joaṣi mú u wá sí Jerusalẹmu. Ó sì wó ògiri Jerusalẹmu lulẹ̀ láti ẹnu-ọ̀nà Efraimu sí igun ẹnu-ọ̀nà apá kan títí ń lọ sí irinwó (400) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn.