1 Kronika 7:30-40
30
Àwọn ọmọ Aṣeri: Imina, Iṣifa, Iṣfi àti Beriah. Arábìnrin wọn sì jẹ́ Sera.
31
Àwọn ọmọ Beriah: Heberi àti Malkieli, tí ó jẹ́ baba Barsafiti.
32
Heberi jẹ́ baba Jafileti, Ṣomeri àti Hotami àti ti arábìnrin wọn Ṣua.
33
Àwọn ọmọ Jafileti: Pasaki, Bimhali àti Asifati. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Jafileti.
34
Àwọn ọmọ Ṣomeri: Ahi, Roga, Jahuba àti Aramu.
35
Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Helemu Sofahi, Imina, Ṣeleṣi àti Amali.
36
Àwọn ọmọ Sofahi: Sua, Haniferi, Ṣuali, Beri, Imra.
37
Beseri, Hodi, Ṣamma, Ṣilisa, Itrani àti Bera.
38
Àwọn ọmọ Jeteri: Jefunne, Pisifa àti Ara.
39
Àwọn ọmọ Ulla: Arah, Hannieli àti Resia.
40
Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ìran ọmọ Aṣeri—olórí ìdílé, àṣàyàn ọkùnrin, alágbára jagunjagun àti olórí nínú àwọn ìjòyè. Iye àwọn tí a kà yẹ fún ogun, gẹ́gẹ́ bí à ti ṣe kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìdílé wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàlá (26,000) ọkùnrin.
Settings