Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wives: Are a blessing to husbands

3 ẹsẹ · 37 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Are a blessing to husbands

  1. Aya oníwà rere ni adé ọkọ rẹ̀ ṣùgbọ́n aya adójútini dàbí inú egungun rẹ̀ jẹrà.

  2. Ta ni ó le rí aya oníwà rere? Ó níye lórí ju iyùn lọ.

  3. Ire ní ó ń ṣe fún un, kì í ṣe ibi ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.