Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Widows: Woe to those who oppress
Àwọn ẹsẹ nípa Woe to those who oppress
Ègbé ni fún àwọn ti ń ṣe òfin àìṣòdodo,
láti dún àwọn aláìní ní ẹ̀tọ́ wọn àti láti fa ọwọ́ ìdájọ́ sẹ́yìn kúrò níwájú àwọn olùpọ́njú ènìyàn mi, wọ́n sọ àwọn ọ̀pọ̀ di ìjẹ fún wọn, wọ́n sì ń ja àwọn aláìní baba lólè.