Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Weeks: The feast of pentecost called the feast of weeks
Àwọn ẹsẹ nípa The feast of pentecost called the feast of weeks
“Ṣe àjọ ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú àkọ́so èso alikama àti àjọ ìkórè ní òpin ọdún.
Nígbà tí ọjọ́ Pentikosti sì dé, gbogbo wọn fi ọkàn kan wà ní ibìkan.