Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wave Offering: Was to be eaten in a holy place by the priest's family

1 ẹsẹ · 12 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Was to be eaten in a holy place by the priest's family

  1. Ṣùgbọ́n ìwọ àti àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin rẹ le jẹ igẹ̀ ẹran tí a fì níwájú Olúwa àti itan tí wọ́n gbé síwájú Olúwa, kí ẹ jẹ wọ́n ní ibi tí a kà sí mímọ́, èyí ni a ti fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ gẹ́gẹ́ bí ìpín yín nínú ẹbọ àlàáfíà àwọn ara Israẹli.