Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Wave Offering: Of the fat, &c of the consecration ram burnt on the altar

2 ẹsẹ · 12 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Of the fat, &c of the consecration ram burnt on the altar

  1. Nígbà náà ni ìwọ yóò sì gbà wọ́n ní ọwọ́ wọn, ìwọ yóò sì sun wọ́n lórí pẹpẹ pẹ̀lú ẹbọ sísun fún òórùn dídùn níwájú Olúwa, ẹbọ ti a fi iná sun sí Olúwa.

  2. Lẹ́yìn náà, Mose gba gbogbo rẹ̀ lọ́wọ́ wọn, ó sì sun wọn lórí ẹbọ sísun tó wà lórí pẹpẹ gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ìfinijoyè àlùfáà òórùn dídùn, ẹbọ tí a fi iná sun sí Olúwa.