Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Watchfulness: Illustrated
Àwọn ẹsẹ nípa Illustrated
“Ẹ di àmùrè yín, kí fìtílà yín sì máa jó.
Kí ẹ̀yin tìkára yín dàbí ẹni tí ń retí olúwa wọn, nígbà tí òun ó padà ti ibi ìgbéyàwó dé, pé nígbà tí ó bá dé, tí ó sì kànkùn, kí wọn lè ṣí i sílẹ̀ fún un lọ́gán.