Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Vanity: The conduct of the ungodly is
Àwọn ẹsẹ nípa The conduct of the ungodly is
Níwọ̀n bí ẹ̀yin ti mọ̀ pé a kò fi ohun ìdíbàjẹ́ rà yín padà, bí fàdákà tàbí wúrà kúrò nínú ìwà asán yín, tí ẹ̀yin ti jogún láti ọ̀dọ̀ àwọn baba yín.