Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Vanity: Judicially given up to
Àwọn ẹsẹ nípa Judicially given up to
O fi òpin sí ayé wọn nínú asán àti ọdún wọn nínú ìpayà.
Nígbà tí ẹ bá kígbe fún ìrànlọ́wọ́ ẹ jẹ́ kí àkójọ àwọn ère yín gbà yín! Atẹ́gùn yóò gbá gbogbo wọn lọ, èémí lásán làsàn ni yóò gbá wọn lọ. Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá fi mí ṣe ààbò rẹ̀ ni yóò jogún ilẹ̀ náà yóò sì jogún òkè mímọ́ mi.”