Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Urim and Thummin: Placed in the breastplate of the high priest

2 ẹsẹ · 6 abala

Wá "Urim and Thummin"

Àwọn ẹsẹ nípa Placed in the breastplate of the high priest

  1. Bákan náà ìwọ yóò sì mu Urimu àti Tumimu sínú ìgbàyà, kí wọn kí ó wà ní ọkàn Aaroni nígbàkígbà tí ó bá ń wólẹ̀ níwájú Olúwa. Aaroni yóò sì máa ru ohun ti a ń fi ṣe ìpinnu fún àwọn ọmọ Israẹli ní ọkàn rẹ̀ nígbà gbogbo níwájú Olúwa.

  2. Ó fi ìgbàyà sí àyà rẹ̀, ó sì fi Urimu àti Tumimu sí ibi ìgbàyà náà.