Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trespass Offering: For rash swearing

1 ẹsẹ · 25 abala

Àwọn ẹsẹ nípa For rash swearing

  1. Tàbí bí ẹni kan bá búra láti ṣe ohun kan láì ronú lé e lórí, yálà ohun tó dára tàbí ohun búburú, nínú ọ̀rọ̀ yówù tó ti búra láì kíyèsi ara, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, kò mọ̀ nípa rẹ̀ tẹ́lẹ̀, bí ó ti wù kó rí, nígbà tó bá mọ̀ yóò jẹ̀bi.