Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Trespass Offering: For concealing knowledge of a crime
Àwọn ẹsẹ nípa For concealing knowledge of a crime
“ ‘Bí ẹnìkan bá dẹ́ṣẹ̀ nítorí pé kò sọ̀rọ̀ nígbà tí a bi í ní gbangba pé kó jẹ́rìí nípa nǹkan tó rí tàbí nǹkan tó mọ̀ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ kan, a ó di ẹ̀bi rẹ̀ rù ú.