Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Tithe: The tenth of, offered by the Levites as an heave offering to God

2 ẹsẹ · 20 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The tenth of, offered by the Levites as an heave offering to God

  1. “Sọ fún àwọn ọmọ Lefi kí o sì wí fún wọn pé: ‘Nígbà tí ìdámẹ́wàá bá ń wọlé láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Israẹli gẹ́gẹ́ bí ogún rẹ. O gbọdọ̀ mú ìdámẹ́wàá lára rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọrẹ Olúwa.

  2. A ó ka ọrẹ rẹ gẹ́gẹ́ bí ọkà irúgbìn láti ilẹ̀ ìpakà tàbí wáìnì láti fún wa.