Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Roman Empire: Legs of iron in Nebuchadnezzar's vision

2 ẹsẹ · 42 abala

Wá "The Roman Empire"

Àwọn ẹsẹ nípa Legs of iron in Nebuchadnezzar's vision

  1. àwọn ẹsẹ̀ rẹ̀ jẹ́ irin, àwọn àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ̀ jẹ́ apá kan irin àti apá kan amọ̀.

  2. Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ìjọba kẹrin yóò wà, ìjọba náà yóò lágbára bí irin, gẹ́gẹ́ bí irin ti í fọ́, tó sì ń lọ gbogbo nǹkan àti bí irin ti í fọ́ nǹkan sí wẹ́wẹ́, bẹ́ẹ̀ ni yóò fọ́ tí yóò sì lọ gbogbo àwọn tókù.