Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Roman Empire: Criminals delivered over to the soldiers for execution

2 ẹsẹ · 42 abala

Wá "The Roman Empire"

Àwọn ẹsẹ nípa Criminals delivered over to the soldiers for execution

  1. Nígbà náà ni Pilatu dá Baraba sílẹ̀ fún wọn. Lẹ́yìn tí òun ti na Jesu tán, ó fi í lé wọn lọ́wọ́ láti mú un lọ kàn mọ́ àgbélébùú.

  2. Nígbà náà ni àwọn ọmọ-ogun gómìnà mú Jesu lọ sí gbọ̀ngàn ìdájọ́ wọ́n sì kó gbogbo ẹgbẹ́ ọmọ-ogun tì í.