Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Palm Tree: Tents often pitched under the shade of

1 ẹsẹ · 18 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Tents often pitched under the shade of

  1. Òun a máa jókòó ṣe ìdájọ́ ní abẹ́ igi ọ̀pẹ tí a sọ orúkọ rẹ̀ ní ọ̀pẹ Debora láàrín Rama àti Beteli ní ilẹ̀ òkè Efraimu, àwọn ará Israẹli a sì máa wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ láti yanjú èdè-àìyedè tí wọ́n bá ní sí ara wọn, tàbí láti gbọ́ ohùn Olúwa láti ẹnu rẹ̀.