Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Palm Tree: Blasted as a punishment
Àwọn ẹsẹ nípa Blasted as a punishment
Àjàrà gbẹ, igi ọ̀pọ̀tọ́ sì rọ̀ dànù; igi pomegiranate, igi ọ̀pẹ pẹ̀lú, àti igi apiili, gbogbo igi igbó ni o rọ. Nítorí náà ayọ̀ ọmọ ènìyàn gbẹ kúrò lọ́dọ̀ wọn.