Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Feast of Pentecost: The Holy Spirit given to apostles at

3 ẹsẹ · 14 abala

Wá "The Feast of Pentecost"

Àwọn ẹsẹ nípa The Holy Spirit given to apostles at

  1. Nígbà tí ọjọ́ Pentikosti sì dé, gbogbo wọn fi ọkàn kan wà ní ibìkan.

  2. Lójijì ìró sì ti ọ̀run wá, gẹ́gẹ́ bí ìró ẹ̀fúùfù líle, ó sì kún gbogbo ilé níbi tí wọ́n gbé jókòó.

  3. Ẹ̀là ahọ́n bí i iná sì yọ sí wọn, ó pín, ó sì bà lé olúkúlùkù wọn.