Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Stones: Prepared in the quarries
Àwọn ẹsẹ nípa Prepared in the quarries
Ní kíkọ́ ilé náà, òkúta tí a ti gbẹ́ sílẹ̀ kí a tó mú un wá ibẹ̀ nìkan ni a lò, a kò sì gbúròó òòlù tàbí àáké tàbí ohun èlò irin kan nígbà tí a ń kọ́ ọ lọ́wọ́.