Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Soldiers: Their duty as sentinels

1 ẹsẹ · 13 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Their duty as sentinels

  1. Nígbà tí Herodu sì wá a kiri, tí kò sì rí i, ó wádìí àwọn ẹ̀ṣọ́, ó pàṣẹ pé, kí a pa wọ́n. Herodu sì sọ̀kalẹ̀ láti Judea lọ sí Kesarea, ó sì wà níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀.