Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sincerity: Our love to God

2 ẹsẹ · 28 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Our love to God

  1. Kì í ṣe nípa àṣẹ ni mo fi ń sọ ọ́, ṣùgbọ́n kí a lè rí ìdí òtítọ́ ìfẹ́ yín pẹ̀lú, nípa iṣẹ́ ìyìnrere ẹlòmíràn.

  2. Nítorí náà ẹ fi ẹ̀rí ìfẹ́ yín hàn wọ́n níwájú ìjọ, àti ìṣògo wa nítorí yín.