Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sin Offering: Was eaten by the priests in a holy place, when its blood had not been brought into the tabernacle

3 ẹsẹ · 25 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Was eaten by the priests in a holy place, when its blood had not been brought into the tabernacle

  1. Àlùfáà tó rú ẹbọ náà ni kí ó jẹ ẹ́, ibi mímọ́ ni kí ó ti jẹ ẹ́, ní àgbàlá àgọ́ ìpàdé.

  2. Gbogbo ọkùnrin ní ìdílé àlùfáà ló lè jẹ ẹ́, ó jẹ́ mímọ́ jùlọ.

  3. Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ kankan, èyí tí wọ́n bá mú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sínú àgọ́ ìpàdé láti fi ṣe ètùtù ní Ibi Mímọ́, sísun ni kí ẹ sun ún.