Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shimei: 1. Called Shimi, son of Gershon
Àwọn ẹsẹ nípa 1. Called Shimi, son of Gershon
Àwọn ọmọ Gerṣoni ni ìran wọn ni: Libni àti Ṣimei.
Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.
Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.
Àwọn tí ó jẹ́ ọmọ Gerṣoni: Laadani àti Ṣimei.
Àti ọmọ Ṣimei: Jahati, Sina, Jeuṣi àti Beriah. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Ṣimei mẹ́rin ni gbogbo wọn.