Skip to content

Laadan

9 ẹsẹ · 3 ọmọ ẹbí

A tún mọ̀ ọ́n sí: Libni, Jahath

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Laadan

  1. Àwọn ọmọ Gerṣoni ni ìran wọn ni: Libni àti Ṣimei.

  2. Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.

  3. Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Gerṣoni: Libni àti Ṣimei.

  4. Ti Gerṣoni: Libni ọmọkùnrin rẹ̀, Jahati. Ọmọkùnrin rẹ̀, Simma ọmọkùnrin rẹ̀,

  5. ọmọ Jahati, ọmọ Gerṣoni, ọmọ Lefi;

  6. Àwọn tí ó jẹ́ ọmọ Gerṣoni: Laadani àti Ṣimei.

  7. Àwọn ọmọ Laadani Jehieli ẹni àkọ́kọ́, Setamu àti Joẹli, mẹ́ta ní gbogbo wọn.

  8. Àwọn ọmọ Ṣimei: Ṣelomiti, Hasieli àti Harani mẹ́ta ní gbogbo wọn. Àwọn wọ̀nyí sì ni olórí àwọn ìdílé Laadani.

  9. Àwọn ìran ọmọ Laadani tí wọn jẹ́ ará Gerṣoni nípasẹ̀ Laadani àti tí wọn jẹ́ àwọn olórí àwọn ìdílé tí ó jẹ́ ti Laadani ará Gerṣoni ni Jehieli.