Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shewbread: Placed in the north side of the tabernacle
Àwọn ẹsẹ nípa Placed in the north side of the tabernacle
Mose gbé tábìlì sínú àgọ́ àjọ sí ìhà àríwá àgọ́ náà lẹ́yìn aṣọ títa,
A gbé àgọ́ kan dìde. Nínú yàrá rẹ̀ àkọ́kọ́ ni a ti rí ọ̀pá fìtílà, tábìlì, àti àkàrà ìfihàn. Èyí tí a ń pè ní ibi mímọ́.