Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shechaniah: 4. Father of Shemaiah. Possibly identical with 1 above
Àwọn ẹsẹ nípa 4. Father of Shemaiah. Possibly identical with 1 above
Lẹ́yìn wọn, Sadoku ọmọ Immeri tún ọ̀kánkán òdìkejì ilé rẹ̀ ṣe. Lẹ́yìn rẹ̀ ni Ṣemaiah ọmọ Ṣekaniah, olùṣọ́ ibodè ìhà ìlà-oòrùn ṣe àtúnṣe.