Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shechaniah: 3. A Jew who proposed to Ezra the putting away of Gentile wives
Àwọn ẹsẹ nípa 3. A Jew who proposed to Ezra the putting away of Gentile wives
Nígbà náà ni Ṣekaniah ọmọ Jehieli, ọ̀kan lára ìran Elamu, sọ fún Esra pé, “Àwa ti jẹ́ aláìṣòótọ́ sí Ọlọ́run wa nípa fífẹ́ àwọn obìnrin àjèjì láàrín àwọn ènìyàn tí ó wà yí wa ká. Ṣùgbọ́n síbẹ̀ náà, ìrètí sì wà fún Israẹli