Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Self-Delusion: Christ shall not come to judge
Àwọn ẹsẹ nípa Christ shall not come to judge
Wọn ó sì máa wí pé, “Níbo ni ìlérí wíwà rẹ̀ gbé wà? Láti ìgbà tí àwọn baba ti sùn, ohun gbogbo ń lọ bí wọ́n ti wà rí láti ìgbà ọjọ́ yìí wá.”