Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salt: Elisha healed the bad water with
Àwọn ẹsẹ nípa Elisha healed the bad water with
Nígbà náà ó sì jáde lọ sí ibi orísun omi, ó sì da iyọ̀ sí inú rẹ̀, ó wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Èmi ti wo omi yìí sàn. Kò ní mú ikú wá mọ́ tàbí mú ilẹ̀ náà sá.’ ”